![]() Login With Facebook Or Please Join Naijapals! or Login
← Back | Music Library
Play / DL → ( 273915 plays)Uhhhuhhhh Uhuh Ijoba orun Ere Onigbagbo o Ijoba orun Ere Onigbagbo o Ma je n kuna Baba Mu mi dele o Ma je n kuna Baba se Mu mi dele o Owo ti mo ni ko le mu mi dele o Moto ti mo ri ra ko le wa mi dele o Ore ti mo ni ko le sinmi dele o Gbogbo iwe ti mo ri ka won o le gbe mi dele o Ma je n kuna Baba Mu mi dele o ki n ma ku sajo bi efin Mu mi dele o Aye loja, oorun ni ile Mu mi dele o Aye loja yi, oorun nile se Mu mi dele o Mu mi dele o (x8) Ma ma je n kuna Baba ooo Baba ooo Mu mi dele o (x5) Ile ogo Ile ayo, Ile ayo Ile alafia Ile ogo Ile ayo, Ile ayo Ile alafia Ijoba orun Ere onigbagbo o Ijoba oorun Ere onigbagbo o Ma je n kuna Copy Link: rating: 4 stars/63 ratings Tweet Comments:~ 13 years ago
ladytobago said: ALL JNSPIRING!!! A very graceful singer, lover her from the first time i heard her, she has a very sooting and peaceful voice. This song helps me relax and forget all the worries and cares. Lara thank you and may God contoinue to inspire you to keep on singing for him. ~ 12 years ago
Lynsumba said: Amazing!!! Worship is worship,no matter the language...though i dont understand a word,i feel the song-drwas one close to God's Throne...;Thx Lara...bless u... Add CommentPlease Login To Add Comment |
Follow @Naijapals |