![]() Login With Facebook Or Please Join Naijapals! or Login
← Back | Music Library
Play / DL → ( 44514 plays)Nigerian gospel singer, Tobi Alabi comes through with a new release, she titled “Logan Ti Ode” featuring TY Bello and George. On her Spontaneous Worship series and this one remains just as powerful and spirit moving as the rest. The song was produced by George While the music video directed by Taiwo Apatira and Adelodun Akinwale. [COMPLETE LYRICS] Logan ti o de audio by tope alabi download download Spontaneous by Ty Bello & Tope alabi Logan ti ode by tope alabi download Spontaneous by Ty Bello & Tope alabi Logan ti ode by tope alabi download logan ti ode by tope alabi Logan.Tope Alabi logan ti o de tope alabi logan ti ode ft.ty bello and george tope alabi logan ti ode logan tope alabi download audio logan to de by tope Alabi download logan by tope alabi tope alabi logan ti ode (Verse) Emi mo oun oju mi tiri, mo mo oun eti mi ti gbo Mo oun oju mi tiri, mo mo oun eti mi ti gbo Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala, aye mi le to Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala, aye mi le to Mo mo oun aye ma ti wi, mo mo oun eyan ma ti so Won ti pe wa ni agan ri, boya won ti pewa lo’olosi ri Sugbon, logan ti o de o Olugbala, aye mi le to Logan ti o de o Olugbala, aye e le to Aye to ti daru tele tele o, logan ti o de Oro ti eniyan ti fi s’alufani re, logan ti o de Oro ti ko dara ta ti so si o, logan ti o de Oruko ti kin se tire ta ti pe o, logan ti o de Ani logan ti o de o Olugbala, aye e le to Logan ti o de o Olugbala, aye e le to Logan ti Jesu de o Olugbala, l’aye e le to Ko s’oruko t’aye o le pe ni, wa ma peni l’agan l’ona gbo gbo Bo ba lowo lowo agan ni, bo ba bi mo o agan ni Bo ba tegba ko dagba agan lo je, sugbon logan ti o de, sope logan ti o de Ani logan ti o de, lesekese, logan ti o de Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to Logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to Instantly lo’n je be, bo se n debe, won de yi oruko pada Logan ti o de, eheheh logan ti o de, eyin ta pe l’agan e ma so wi pe, logan ti o de Awon ta ti fi oruko aburu pe ni’le won yi, logan ti o de Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to Logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to Ani eheh, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to Ani, logan ti o de o aseda, l’aye mi le to Ani, logan ti o de o Olorun o, l’aye mi le to Irawo owuro omo Marry yo sinu oro mi, l’aye mi le to Ah, alagbara ni Shiloh loba ran ti mi si rere, l’aye mi le to Enu mi wa kun fu eri o gbogbo, l’aye mi le to Aye mi gba iyipada otun o logan to de, , l’aye mi le to Aye mi ba leto l’ota ba wo Iran mi, l’aye mi le to Aye mi le to lo ta bawo Iran mi, l’aye mi le to Ota kaworo, enu won gbe tan lori oju kan, l’aye mi le to Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to (Outro) Thank you Lord Jesus for all that you are.. Copy Link: rating: 5 stars/1 ratings Tweet No comments yet Add CommentPlease Login To Add Comment |
Follow @Naijapals |