Naijapals Mobile

Or Please Join Naijapals! or Login
← Back | Music Library

Supplications / Olayinka Janet and Juliet


Play / DL → ( 11182 plays)


(Percussions)
Igbagbọ mi duro l'ẹjẹ Jesu
Ọlọrun mi jọwọ je k'igbagbọ gbe mi o he.
Ojumọ ti mọ, mo ngb'adura
Ọlọrun mi, Ẹlẹda mi,
Jẹ ka ri anu Rẹ gba.
(Interlude)
L'ọjọ iṣẹ ati ọjọ aiṣe,
Ọlọrun mi, Ẹlẹda mi,
Jẹ ka r' ibunkun Rẹ gba.
Alẹ ti de, ilẹ ti ṣu,
Ọlọrun mi, Ẹlẹda mi,
Ma ṣai d'abo Rẹ bo wa.
(Interlude)
Igbagbọ mi duro l'ẹjẹ Jesu
Ọlọrun mi jọwọ je k'igbagbọ gbe mi o he.
(Percussions)


Copy Link:


rating: 5 stars/1 ratings





No comments yet

Add Comment

Please Login To Add Comment
NP mob 2009 - 2024. Full site - T: @naijapals - F: Naijapals - Whatsapp